Rom 2:22 YCE

22 Iwọ ti o nwipe ki enia ki o máṣe panṣaga, iwọ nṣe panṣaga? iwọ ti o ṣe họ̃ si oriṣa, iwọ njà tẹmpili li ole?

Ka pipe ipin Rom 2

Wo Rom 2:22 ni o tọ