Rom 3:9 YCE

9 Njẹ ki ha ni? awa ha san jù wọn bi? Kò ri bẹ̃ rara: nitori a ti fihan ṣaju pe ati awọn Ju ati awọn Hellene, gbogbo nwọn li o wà labẹ ẹ̀ṣẹ;

Ka pipe ipin Rom 3

Wo Rom 3:9 ni o tọ