Rom 4:12 YCE

12 Ati baba ikọla fun awọn ti kò si ninu kìki awọn akọla nikan, ṣugbọn ti nrin pẹlu nipasẹ igbagbọ́ Abrahamu baba wa, ti o ni li aikọla.

Ka pipe ipin Rom 4

Wo Rom 4:12 ni o tọ