Rom 6:23 YCE

23 Nitori ikú li ère ẹ̀ṣẹ; ṣugbọn ẹ̀bun ọfẹ Ọlọrun ni ìye ti kò nipẹkun, ninu Kristi Jesu Oluwa wa.

Ka pipe ipin Rom 6

Wo Rom 6:23 ni o tọ