Rom 7:18 YCE

18 Nitori emi mọ̀ pe ko si ohun rere kan ti ngbe inu mi, eyini ninu ara mi: nitori ifẹ ohun ti o dara mbẹ fun mi, ṣugbọn ọna ati ṣe e li emi kò ri.

Ka pipe ipin Rom 7

Wo Rom 7:18 ni o tọ