Rom 7:2 YCE

2 Nitori obinrin ti o ni ọkọ, ìwọn igbati ọkọ na wà lãye, a fi ofin dè e mọ́ ọkọ na; ṣugbọn bi ọkọ na ba kú, a tú u silẹ kuro ninu ofin ọkọ na.

Ka pipe ipin Rom 7

Wo Rom 7:2 ni o tọ