Rom 7:23 YCE

23 Ṣugbọn mo ri ofin miran ninu awọn ẹ̀ya ara mi, ti mba ofin inu mi jagun ti o si ndì mi ni igbekun wá fun ofin ẹ̀ṣẹ, ti o mbẹ ninu awọn ẹ̀ya ara mi.

Ka pipe ipin Rom 7

Wo Rom 7:23 ni o tọ