Rom 8:10 YCE

10 Bi Kristi ba si wà ninu nyin, ara jẹ okú nitori ẹ̀ṣẹ: ṣugbọn ẹmí jẹ iyè nitori ododo.

Ka pipe ipin Rom 8

Wo Rom 8:10 ni o tọ