Rom 8:15 YCE

15 Nitori ẹnyin kò tun gbà ẹmí ẹrú lati mã bẹ̀ru mọ́: ṣugbọn ẹnyin ti gbà ẹmí isọdọmọ, nipa eyi ti awa fi nke pé, Abba, Baba.

Ka pipe ipin Rom 8

Wo Rom 8:15 ni o tọ