Rom 8:29 YCE

29 Nitori awọn ẹniti o ti mọ̀ tẹlẹ, li o si ti yàn tẹlẹ lati ri bi aworan Ọmọ rẹ̀, ki on le jẹ akọbi larin awọn arakunrin pupọ.

Ka pipe ipin Rom 8

Wo Rom 8:29 ni o tọ