Rom 8:32 YCE

32 Ẹniti kò da Ọmọ on tikararẹ̀ si, ṣugbọn ti o jọwọ rẹ̀ lọwọ fun gbogbo wa, yio ha ti ṣe ti kì yio fun wa li ohun gbogbo pẹlu rẹ̀ lọfẹ?

Ka pipe ipin Rom 8

Wo Rom 8:32 ni o tọ