Rom 9:15 YCE

15 Nitori o wi fun Mose pe, Emi ó ṣãnu fun ẹniti emi ó ṣãnu fun, emi o si ṣe iyọ́nu fun ẹniti emi o ṣe iyọ́nu fun.

Ka pipe ipin Rom 9

Wo Rom 9:15 ni o tọ