Rom 9:27 YCE

27 Isaiah si kigbe nitori Israeli pe, Bi iye awọn ọmọ Israeli bá ri bi iyanrin okun, apakan li a ó gbala.

Ka pipe ipin Rom 9

Wo Rom 9:27 ni o tọ