Dáníẹ́lì 10:14 BMY

14 Ní ìsinsinyí mo wá láti ṣàlàyé ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwọn ènìyàn rẹ ní ọjọ́ iwájú, nítorí ìran náà ń sọ nípa ọjọ́ iwájú.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:14 ni o tọ