Dáníẹ́lì 10:16 BMY

16 Nígbà náà, ni ẹnìkan tí ó rí bí ènìyàn fi ọwọ́ kan ètè mi, mo la ẹnu mi, mo sì bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ ọ̀rọ̀, mo sọ fún ẹni tí ó dúró níwájú mi, “Ìrònú sì mú mi, nítorí ìran náà, Olúwa mi, n kò sì ní okun.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 10

Wo Dáníẹ́lì 10:16 ni o tọ