Dáníẹ́lì 11:10 BMY

10 Àwọn ọmọ rẹ̀ yóò múra ogun wọn yóò kó ogun ńlá jọ, èyí tí a ó gbá lọ bí àgbàrá omi ńlá, yóò sì gbá a lọ títí dé ìlú olódi rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:10 ni o tọ