Dáníẹ́lì 11:38 BMY

38 Ṣùgbọ́n dípò wọn, yóò bu ọlá fún òrìṣà àwọn ìlú olódi: òrìṣà tí àwọn baba rẹ̀ kò mọ̀ ni yóò bu ọlá fún pẹ̀lú wúrà àti fàdákà, pẹ̀lú òkúta iyebíye àti ẹ̀bùn tí ó lówó lórí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:38 ni o tọ