43 Yóò gba àkóso ìṣúra wúrà àti fàdákà àti gbogbo orò Éjíbítì, pẹ̀lú ti Líbíyà àti Núbíà nígbà tí ó mú wọn tẹríba.
Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11
Wo Dáníẹ́lì 11:43 ni o tọ