Dáníẹ́lì 12:1 BMY

1 “Ní àkókò náà, ni Máíkẹ́lì, ọmọ aládé ńlá, ẹni tí o n dáàbò bo àwọn ènìyàn an rẹ̀, yóò dìde. Àkókò ìpọ́njú yóò wà, irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn orílẹ̀ èdè títí di àkókò náà. Ṣùgbọ́n ní àkókò náà àwọn ènìyàn rẹ̀, gbogbo àwọn tí a bá ti rí orúkọ wọn nínú ìwé ni a ó gbàlà.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 12

Wo Dáníẹ́lì 12:1 ni o tọ