Dáníẹ́lì 12:11 BMY

11 “Láti àkókò tí a ó mú ẹbọ ojoojúmọ́ kúrò, tí a ó sì gbé ìríra tí ó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀ yóò sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún àti igba lé àádọ́rùn-ún ọjọ́ (1,290).

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 12

Wo Dáníẹ́lì 12:11 ni o tọ