Dáníẹ́lì 12:5 BMY

5 Nígbà náà, ni èmi Dáníẹ́lì, wò, ní iwájú mi àwọn méjì mìíràn dúró, ọ̀kan dúró sí apá ìhín ní etí bèbè odò ẹnìkan náà ní apá ọ̀hún etí i bèbè.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 12

Wo Dáníẹ́lì 12:5 ni o tọ