Dáníẹ́lì 2:11 BMY

11 Nǹkan tí ọba béèrè yìí ṣòro púpọ̀. Kò sí ẹni tí ó lè fi han ọba à fi àwọn òrìṣà, tí wọn kì í gbé láàrin ènìyàn.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:11 ni o tọ