Dáníẹ́lì 2:14 BMY

14 Nígbà tí Áríókù, olórí àwọn olùṣọ́ ọba, jáde láti lọ pa àwọn amòye Bábílónì, Dáníẹ́lì sọ̀rọ̀ fún un pẹ̀lú ọgbọ́n àti òye.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:14 ni o tọ