Dáníẹ́lì 2:30 BMY

30 Ṣùgbn fún èmi, a fi àsírí yìí hàn mí, kì í ṣe pé mo ní ọgbọ́n tí ó pọ̀ ju ti alààyè kankan lọ, ṣùgbọ́n nítorí kí ọba lè mọ ìtumọ̀ àlá àti kí ó lè mọ ohun tí ó wà ní ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:30 ni o tọ