Dáníẹ́lì 2:34 BMY

34 Bí ó ṣe ń wò, òkúta kan wá, tí kò wá láti ọwọ́ ẹnìkankan. Ó kọlu ère náà ní àtẹ́lẹṣẹ̀ irin àti amọ̀, ó sì fọ́ wọn sí wẹ́ẹ́wẹ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:34 ni o tọ