Dáníẹ́lì 2:39 BMY

39 “Lẹ́yìn èyí ni ìjọba mìíràn yóò dìde, tí kò ní lágbára tó tìrẹ, lẹ́yìn in rẹ̀, ìjọba kẹta tí yóò dàbí idẹ, èyí tí yóò jọba lórí i gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:39 ni o tọ