Dáníẹ́lì 2:42 BMY

42 Bí ọmọ ìka ẹsẹ̀ ṣe jẹ́ apákan irin àti apákan amọ̀, bẹ́ẹ̀ ni ìjọba yìí yóò lágbára lápákan tí kò sì ní lágbára lápákan.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:42 ni o tọ