Dáníẹ́lì 2:8 BMY

8 Nígbà náà ni ọba sọ pé, “Èmi mọ̀ dájú wí pé ẹ̀yin fẹ́ fi àkókò ṣòfò nítorí pé ẹ̀yin ti mọ̀ pé nǹkan ti lọ ní orí mi:

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 2

Wo Dáníẹ́lì 2:8 ni o tọ