Dáníẹ́lì 3:13 BMY

13 Nígbà náà ni Nebukadinéṣárì pàṣẹ ní ìrunú àti ìbínú pé kí a mú Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò wá, wọ́n sì mú wọn wá síwájú ọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:13 ni o tọ