Dáníẹ́lì 3:16 BMY

16 Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò dá ọba lóhùn wí pé, “Nebukadinéṣárì, kì í ṣe fún wa láti gba ara wa sílẹ̀ níwájú u rẹ nítorí ọ̀rọ̀ yìí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:16 ni o tọ