Dáníẹ́lì 3:19 BMY

19 Nígbà náà ni Nebukadinéṣárì bínú gidigidi sí Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò, ojú u rẹ̀ sì yípadà, ó sì pàṣẹ pé, kí wọn dá iná ìléru náà kí ó gbóná ní ìlọ́po méje ju èyí tí wọn ń dá tẹ́lẹ̀,

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:19 ni o tọ