Dáníẹ́lì 4:31 BMY

31 Bí ọba ṣe ń sọ ọ̀rọ̀ náà lọ́wọ́ ohùn kan wá láti ọ̀run “Ìwọ Nebukadinéṣárì ọba, ìwọ ni a ti pàṣẹ nípa rẹ̀, a ti gba ìjọba à rẹ kúrò ní ọwọ́ ọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:31 ni o tọ