Dáníẹ́lì 4:6 BMY

6 Nígbà náà, ni mo pàṣẹ pé kí a mú gbogbo àwọn amòye Bábílónì wá, kí wọn wá sọ ìtumọ̀ àlá náà fún mi.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:6 ni o tọ