Dáníẹ́lì 5:13 BMY

13 Nigbà náà ni a mú Dáníẹ́lì wá ṣíwájú ọba, ọba sì sọ fún-un wí pé, “Ṣé ìwọ ni Dáníẹ́lì, ọ̀kan lára àwọn tí bàbá mi mú ní ìgbékùn láti Júdà!

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:13 ni o tọ