Dáníẹ́lì 5:15 BMY

15 A ti mú àwọn amòye àti àwọn awòràwọ̀ wá sí iwájú mí kí wọn ba à le è wá ka àkọsílẹ̀ yìí kí wọn sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, ṣùgbọ́n wọn kò le è sọ ìtumọ̀ ohun tí ó jẹ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:15 ni o tọ