Dáníẹ́lì 5:21 BMY

21 A lé e kúrò láàrin ènìyàn, a sì fún un ní ọkàn ẹranko; ó sì ń gbé pẹ̀lú àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì ń jẹ koríko bí i ti màlúù; ìrì ọ̀run sì ṣẹ̀ sí ara rẹ̀, títí tó fi mọ̀ pé, Ọlọ́run Ọ̀gá Ògo ń jọba lórí ìjọba ọmọ ènìyàn, òun sì ń fi fún ẹni tí ó bá wù ú.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:21 ni o tọ