Dáníẹ́lì 5:29 BMY

29 Nígbà náà ni Beliṣáṣárì pàṣẹ pé kí a wọ Dáníẹ́lì ní aṣọ eléṣèé àlùkò, kí a sì fi ẹ̀gbà wúrà sí i lọ́rùn, a sì kéde rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórí kẹta ní ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 5

Wo Dáníẹ́lì 5:29 ni o tọ