Dáníẹ́lì 6:23 BMY

23 Inú ọba dùn gidigidi, ó sì pàṣẹ kí a mú Dáníẹ́lì jáde wá láti inú ihò. Nígbà tí a mú Dáníẹ́lì jáde nínú ihò, kò sí ojú ọgbẹ́ kan ní ara rẹ̀, nítorí tí ó gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 6

Wo Dáníẹ́lì 6:23 ni o tọ