Dáníẹ́lì 6:27 BMY

27 Ó ń yọ ni, ó sì ń gba ni là;ó ń ṣe iṣẹ́ àmì àti ìyanuní ọ̀run àti ní ayé.Òun ló gba Dáníẹ́lì làkúrò lọ́wọ́ agbára kìnnìún.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 6

Wo Dáníẹ́lì 6:27 ni o tọ