Dáníẹ́lì 7:11 BMY

11 “Nígbà náà ni mo bẹ̀rẹ̀ sí ní wò, nítorí àwọn ọ̀rọ̀ ìgbéraga tí ìwo náà ń sọ, mo wò títí a fi pa ẹranko náà, a sì pa á run, a sì jù ú sínú iná tí ń jó.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:11 ni o tọ