Dáníẹ́lì 7:22 BMY

22 títí ẹni ìgbàanì fi dé, ó sì ṣe ìdájọ́ ìdáláre fún àwọn ẹni mímọ́ ọ̀gá ògo, àsìkò náà sì dé nígbà tí àwọn ẹni mímọ́ náà jogun ìjọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:22 ni o tọ