Dáníẹ́lì 8:23 BMY

23 “Ní ìgbà ìkẹyìn ìjọba wọn, nígbà tí ìwà búburú àwọn ọlọ̀tẹ̀ bá burú gidigidi ọba tí ojú u rẹ̀ le koko, balógun rìkísí yóò dìde.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:23 ni o tọ