Dáníẹ́lì 9:5 BMY

5 Àwa ti ṣẹ̀, a sì ti ṣe búburú. Àwa ti hu ìwà búburú, a sì ti ṣe ọ̀tẹ̀, a ti yí padà kúrò nínú àwọn àṣẹ àti àwọn ìlànà rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:5 ni o tọ