Ékísódù 10:21 BMY

21 Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Mósè pé, “Gbé ọwọ́ rẹ sókè sí ojú ọ̀run kí okùnkùn báà le bo gbogbo ilẹ̀ Éjíbítì; àní òkùnkùn biribiri.”

Ka pipe ipin Ékísódù 10

Wo Ékísódù 10:21 ni o tọ