Ékísódù 12:18 BMY

18 Búrẹ́dì ti kò ni ìwúkàrà ni ẹ̀yin yóò jẹ láti ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kọ̀kànlélógún osù àkọ́kọ́.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:18 ni o tọ