Ékísódù 12:36 BMY

36 Olúwa ti mú kí àwọn ènìyàn yìí rí ojú rere àwọn ará Éjíbítì wọ́n sì fún wọn ní ohun tí wọ́n béèrè fún, wọ́n sì ko ẹrù àwọn ará Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:36 ni o tọ