Ékísódù 12:51 BMY

51 Àti pé ní ọjọ́ náà gan-an ni Olúwa mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì gẹ́gẹ́ bí ìpín ìpín wọn.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:51 ni o tọ