Ékísódù 14:23 BMY

23 Àwọn ará Éjíbítì sì ń lépa wọn, gbogbo ẹsin Fáráò, kẹ́kẹ́-ogun àti àwọn ẹlẹ́sin rẹ̀ wọ́ tọ̀ wọ́n lọ sínú òkun.

Ka pipe ipin Ékísódù 14

Wo Ékísódù 14:23 ni o tọ