Ékísódù 14:30 BMY

30 Ni ọjọ́ yìí ni Olúwa gba Ísírẹ́lì là kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Éjíbítì; Ísírẹ́lì sì rí òkú àwọn ará Éjíbítì ni etí òkun.

Ka pipe ipin Ékísódù 14

Wo Ékísódù 14:30 ni o tọ