Ékísódù 14:6 BMY

6 Ó sì di kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó sì kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀,

Ka pipe ipin Ékísódù 14

Wo Ékísódù 14:6 ni o tọ